Gomina Babajide Sanwo-Olu ṣi ni ẹni to jaweolubori ninu idibo Gomina ipinlẹ Eko to waye. Eyi ni idajọ ti igbimọ to n gbẹjọ lori awuyewuye to wa latari idibo ipinlẹ Eko gbe kalẹ ni ilu Eko lọjọ Aje.
Ọrọ ifẹ bi adanwo ni, bayii gan an lọrọ ṣe ri pẹlu Taiwo Cole to wa lati idile gbajumọ lagbegbe Victoria Island niluu Eko ati oṣerebinrin, Wofai Fada. Ori ayelujara sọkutu wọwọ lopin ọsẹ nigba ti ...
Some results have been hidden because they may be inaccessible to you
Show inaccessible results